Olufisayo Oloyede – Olugbala
OLUGBÀLÀ
Olufisayo Oloyede releases a brand New Single Song titled “OLUGBÀLÀ”
Olùgbàlà dwells much on the saving and compassionate nature of God..
Be blessed as you stream and download the song
CONTACT OLUFISAYO OLOYEDE ON +2348036399544
The Song is also available on all music platforms.
LYRICS
Olugbala
olugbala ni oo baba /2ce
Olugbala ni o baba /2ce
Solo 1 :
Leti okun pupa
o nawo agbara
Omi ṣe odi si wọn
lọwọ ọtun ati ni osi
Israeli rin lori ilẹ
Egip rin ti ri sinu okun
Ọlọrun agbara rẹ
ko ma lafiwe
Solo 2:
Ẹ wa sọdọ mi
gbogbo ẹyin ti nṣiṣẹ
Ti a di ẹru wiwọle lori emi a fi isinmi fun yin
Ẹgbẹ ajaga mi si ọrun yin ki ẹ si maa kọ ẹkọ lara mi
nitori onini tutu ati onirẹlẹ ọkan ni emi
Ẹyin o si ri isinmi ani isinmi fun okan yin
….. bridge
OLUFISAYO Oloyede Divine: Oludande ni o baba /2ce
Oludande ni o baba /2ce
Olupese ni o baba /2ce
Olupese ni o baba /2xe
Olutunu ni o baba /2ce
Olutunu ni o baba /2ce
Stream and download below…
TRENDING POST
Beembo Grace – Blessings of God Quality Benson – Gratitude Cry Jesus Micheal ft. Doggy Gizzy – Ikebe Timzking – Obaolore Moopac – Ikore Victor Praiz – Forever Minister GUC – Man Wey God Show Mercy Green Boi – Ifeoma Ozioma CGC – Open My Eyes Olufisayo Oloyede – OlugbalaShare this post with your friends on