Olufisayo Oloyede – Iwo Lo Ga Julo
Nigerian gospel singer, Olufisayo Oloyede released a very powerful song titled “Iwo Lo Ga Julo”
ABOUT THE SONG…….
IWO LO GA JULO (SINGLE RELEASE )
By Minister OLUFISAYO OLOYEDE
OLUFISAYO OLOYEDE releases a heartfelt song of gratitude, a soul-stirring worship anthem that expresses deep appreciation for God’s unwavering love and faithfulness.
Available for streaming, download, and sharing on all music platforms.
LYRICS …
Iwọ lo ga julọ /3ce
Ọlọrun to lana leti okun pupa
Solo 1:
O pe riri jade lati inu airi
oorun duro ni gibioni
Oṣupa ni aja lo ni
ki lẹ o le ṣe , Ki lẹ o le ṣe
Ọlọrun to n jọba lori gbogbo aye
SOLO 2
Ohun oluwa nbẹ lori omi pupọ
Ọlọrun ọga ogo nsAn ara
Ohun oluwa o lagbara
Oluwa ni ọla-nla julọ
SOLO 3
O fa igi kedariya
Ohun rẹ ya owo ina
O mu abo agbonrin biwere
Gbogbo wa n sọrọ ogo rẹ
Kindly share the link to bless others.
Thank you for your unending support..
Stream and download below…
TRENDING POST
Gift Bale – No Gree Callmenimotalahi – Bamise Martins Jackson – True Love Moses Bliss ft. Nathaniel Bassey – Doing Of The Lord Nature – Because of you Davedreal – He found me Jeremy Chidubem – Worthy Lizzy Abioye – your Word Gospel Kay – My consolation Ritta Olayinka-Aro – Streams of Worship (Worship medley)Share this post with your friends on